
OGE SISE NI ILE YORUBA - EduDelightTutors
2020年5月15日 · OGE SISE NI AYE ATIJO. Awon ona wonyii ni a ngba se oge ni ile yoruba ni aye atijo. 1.OSUN KIKUN. Awa yoruba la ni asa osun kikun ni ikawo osun pupa, o dabi atike moju, inu igba ni osun nwa.iya omo tuntun akun osun si owo tabi ese asi kun fun omo re pelu.
OGE SISE NI ILE YORUBA Gege bi eda owo Olodumare, omo eniyan feran nnkaan ti o dara, ti o lewa, ti o si joju ni gbese. Idi ree ti ogee sise fi wopo laarin omo eniyan. Ibaa se laarin awon eniyan alawo dudu tabi awon alawo funfun, aimoye ona ni awon awon eda n gba lati fi kun ewa ti Olorun ti pese fun
Lesson Note on Yoruba JSS1 (Basic 7) Third Term
ORI ORO: OGE SISE NI ILE YORUBA(FASHION) Oge sise je asa imototo ati sise ara losoo. Awon ona ti a n gba se oge laye atijo ati lode-oni. Aso wiwo; Iwe wiwe; Laali lile; Tiroo lile; Osun kikun; Ila kiko; Itoju irun ori; Lilo ohun eso lorisirisi; PATAKI OGE SISE. Read Also. Mathematics Lesson Note JSS1 Second Term.
Lesson Note on Yoruba JSS1 (Basic 7) Second Term
Oge sise je asa imototo ati sise ara losoo. Awon ona ti a n gbe se oge ni ile Yoruba laye atijo. Iwe wiwe:- Eyi maa n mu ara eniyan mo tonitoni bee ni ou san bi kuruna, ara wiwo yoo jinna si eni to ba n we dee de.
YORUBA LANGUAGE JSS1 SECOND TERM LESSON NOTE
2024年12月30日 · 1) Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun – Oluwa ni oluse nnkan . ninu gbolohun apeere; a) Ayinde ra aso. b) Ojo je ewa. 2) Oro oruko maa n wa ni ipo abo ninu gbolohun – Eyi ni eni ti a se nnkan . si ninu gbolohun. Apeere; a) Mo ra oko. b) Onilu lu ilu. 3) Oro-Oruko maa n se ise eyan fun oro oruko miiran. Apeere;
Oge sise ni ona ti a n gba lati se itoju ara wa.Yoruba bo won ni ‘imo toto bori arun mole boye se n bori oru’ Oge ni sise arawa losoo ki o le wuyi . sise oge beere lati inu odede wa bi apeere ,wiwe,gige eekannaowo ati ese,fifo enu wa lojoojumo,ati titoju ayika wa. Ni awujo Yoruba orisirisi ona ni a n gba se ara loge,tabi toju ara wa. PATAKI ...
- [PDF]
OGE SISE - FCT EMIS
OGE SISE Oge -sise ni faari sise, fuja tabi sise afe. Asa ni laarin awon Yoruba. Imototo ni ohun akoko ninu oge-sise awon Yoruba. Imototo ara eni ati ti ayika eni. Awon wonyi ni fifi kan-in-kan-in ati ose we laaro, fifo enu pelu orin/pako, rire eekanna owo ati ese lati igba de gba, fifo irun ori deedee ati fifi ipara pa gbogbo ara ko le jolo.
3RD TERM SS1 YORUBA SCHEME OF WORK AND NOTE
Oge Seise. Aso Ebi; Imototo. Ise ti mo fe lojo iwaju. Ki a to le ko akoyawo lori okookan ori-oro wonyi, a gbodo ni arojnle ohun ti won je, itumo ati itumo won miiran to farasin tabi ohun ti o ni abuda won. A nila ti wo anfaani ati aleebu ki a si fi arojinle ero gbe won kale. IGBELEWON: ko aroko lori Oge sise tabi omi. IWE ITOKASI:
Oge sise je mo asa wiwo aso ati sise itoju ara lati irun ori titi de eekanna ese ni ona ti yoo fi bukun ewa adamo eni . Aso wiwo ni olori oge sise ,o je ona ti a n gba bo asiri ago ara wa ,yato si aso iyile ,tokunrin tobinrin ni won ni aso imurode bi apeere aso okunrin ni wonyii dandogo
Oge Ṣíṣe ni Ile Yorùbá Jss 1 First Term - EduDelightTutors
2019年8月7日 · Oge Ṣíṣe ni Ile Yorùbá Jss 1 First Term - EduDelightTutors
- 某些结果已被删除