Oloye Ramon Adedoyin ko figba kankan san owo ile ẹkọ awọn ọmọ oloogbe naa. Ẹgbọn oloogbe, Adegoke Olugbade, lo sọ eyi fun BBC . Olugbade ni awọn mọlẹbi ko gbọ ohunkohun ...